يوروبا ?? yoroba

11 يوربا Èdè Yorùbá ?? Islam – Aye ẹkọ SunnahLabẹ amojuto Dọkita Haitham Sarhan
اللغة يوربا
Èdè Yorùbá

YouTube

https://youtube.com/playlist?list=PLBFEt29we81TmXBfUZ84bCnDJi6jVTSVz

Facebook
https://www.facebook.com/pg/11-%D9%8A%D9%88%D8%B1%D8%A8%D8%A7-%D8%AF%D9%87%D9%8A%D8%AB%D9%85-DHaythem-sarhan-Yoruba-2155250694788452/community/

Telegram
https://t.me/nigerian0

?https://sarhaan.com/a/%d9%8a%d9%88%d8%b1%d9%88%d8%a8%d8%a7-yoroba/

site
https://alsarhaan.com/yrb

لغة يُورُبا هي لغة تستخدم جنوب الصحراء الكبرى. تعد اللغة الأم بالنسبة لشعب يوربا، وهي لغة رسمية في نيجيريا. تستخدم في نيجيريا، وبنين، وتوغو، وسيراليون. كما تستخدمها بعض الجاليات في البرازيل، المعروفين هناك باسم “Lukumi”، وفي كوبا (من قبل جالية “Nago”). تعتبر اللغة من اللغات البنوية الكونغولية المتفرعة من العائلة اللغوية النيجيرية الكونغولية. يستخدمها اليوم أكثر من 20 مليون شخص. وهي لغة نغمية.

Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́

Share this book                 Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́: Ìwé kan ní èdè Yorùbá, tí Dókítà Haitham Sarhan kọ, ní èrò láti kọ́ ọmọ Mùsùlùmí ní àwọn ofin ẹ̀sìn, ìwà àti ẹkọ Islam, lọna todun, tíó fani mọ́ra, Awọn ọrọ inu ẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé, osi lọ ni ìlànà òfin sharia, pẹlu sise akiyesi ifẹ ọmọde fun ere idaraya […]

Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́ Read More »

Aprender a caligrafia árabe a caligrafia do nobre Al- Qur_an

Share this book                 Ọrọ soki nipa iwe naa. Kikọ nipa bi asen kọ Larubawa ati Juzhu A’mma inu Al-Qur’an Alapọnle: Iwe kan ni, tia kọ ni ede yoruba, ti Dokita Haitham Sarhan se, ogbero lati kọwa ni bi asen fi ọwọ kọ larubawa nipasẹ bibẹrẹ pẹlu kiko awọn lẹta ati isesi wọn loriṣiriṣi, lẹhinna okọwa bi

Aprender a caligrafia árabe a caligrafia do nobre Al- Qur_an Read More »

Bi aṣen ṣe Aluwala olomi, ati Aluwala oni yẹpẹ, ati iwẹ

Share this book                 Apejuwe aluwala olomi ati oniyẹpẹ ati iwẹwẹ ghusl: Aworan rẹ ni ede Yoruba, Sheikh Dr. Haitham Sarhan lo pese rẹ, On bẹ ninu ẹ, ọrọ ṣoki nipa apejuwe aluwala olomi ati oniyẹpẹ ati iwẹwẹ ghusl ti Anabi, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa, pẹlu awọn aworan alapejuwe. صفة الوضوء والتيمم والغسل:لوحة

Bi aṣen ṣe Aluwala olomi, ati Aluwala oni yẹpẹ, ati iwẹ Read More »

Bi Anabi sen kirun (Ike Olohun ati Ola olohun koma ba)

Bi Anabi sen kirun Ike Olohun ati Ola olohun koma ba

Share this book                 Apejuwe bi Anabi sen kirun, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa: Aworan rẹ ni ede Yoruba Sheikh Dr. Haitham Sarhan lo pese rẹ, On bẹ ninu ẹ, ọrọ ṣoki nipa apejuwe bi Anabi sen kirun, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa, lati ibi kabara titi de ibi salamọ, gẹgẹ

Bi Anabi sen kirun Ike Olohun ati Ola olohun koma ba Read More »

Scroll to Top