AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA
Share this book AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA http://alsarhaan.com/
AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA Read More »
11 يوربا Èdè Yorùbá ?? Islam – Aye ẹkọ SunnahLabẹ amojuto Dọkita Haitham Sarhan
اللغة يوربا
Èdè Yorùbá
YouTube
https://youtube.com/playlist?list=PLBFEt29we81TmXBfUZ84bCnDJi6jVTSVz
Telegram
https://t.me/nigerian0
?https://sarhaan.com/a/%d9%8a%d9%88%d8%b1%d9%88%d8%a8%d8%a7-yoroba/
site
https://alsarhaan.com/yrb
لغة يُورُبا هي لغة تستخدم جنوب الصحراء الكبرى. تعد اللغة الأم بالنسبة لشعب يوربا، وهي لغة رسمية في نيجيريا. تستخدم في نيجيريا، وبنين، وتوغو، وسيراليون. كما تستخدمها بعض الجاليات في البرازيل، المعروفين هناك باسم “Lukumi”، وفي كوبا (من قبل جالية “Nago”). تعتبر اللغة من اللغات البنوية الكونغولية المتفرعة من العائلة اللغوية النيجيرية الكونغولية. يستخدمها اليوم أكثر من 20 مليون شخص. وهي لغة نغمية.
Share this book AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA http://alsarhaan.com/
AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA Read More »
Share this book AWỌN ADUA TI WỌN JẸ AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA http://alsarhaan.com/
AWỌN ADUA TI WỌN JẸ AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA Read More »
Share this book Apejuwe bi Anabi sen kirun, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa: Aworan rẹ ni ede Yoruba Sheikh Dr. Haitham Sarhan lo pese rẹ, On bẹ ninu ẹ, ọrọ ṣoki nipa apejuwe bi Anabi sen kirun, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa, lati ibi kabara titi de ibi salamọ,
Bi Anabi sen kirun Ike Olohun ati Ola olohun koma ba Read More »
Share this book Apejuwe aluwala olomi ati oniyẹpẹ ati iwẹwẹ ghusl: Aworan rẹ ni ede Yoruba, Sheikh Dr. Haitham Sarhan lo pese rẹ, On bẹ ninu ẹ, ọrọ ṣoki nipa apejuwe aluwala olomi ati oniyẹpẹ ati iwẹwẹ ghusl ti Anabi, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa, pẹlu awọn aworan alapejuwe. صفة الوضوء والتيمم
Bi aṣen ṣe Aluwala olomi, ati Aluwala oni yẹpẹ, ati iwẹ Read More »
Share this book Ọrọ soki nipa iwe naa. Kikọ nipa bi asen kọ Larubawa ati Juzhu A’mma inu Al-Qur’an Alapọnle: Iwe kan ni, tia kọ ni ede yoruba, ti Dokita Haitham Sarhan se, ogbero lati kọwa ni bi asen fi ọwọ kọ larubawa nipasẹ bibẹrẹ pẹlu kiko awọn lẹta ati isesi wọn loriṣiriṣi, lẹhinna okọwa
Aprender a caligrafia árabe a caligrafia do nobre Al- Qur_an Read More »
Share this book Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́: Ìwé kan ní èdè Yorùbá, tí Dókítà Haitham Sarhan kọ, ní èrò láti kọ́ ọmọ Mùsùlùmí ní àwọn ofin ẹ̀sìn, ìwà àti ẹkọ Islam, lọna todun, tíó fani mọ́ra, Awọn ọrọ inu ẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé, osi lọ ni ìlànà òfin sharia, pẹlu sise akiyesi ifẹ ọmọde fun ere
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́ Read More »
Share this book Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa: Iwe kan ni, ni Ede Yoruba ti Dokita Haitham Sarhan kọ, o ṣe alaye tira Awọn ipinlẹ mẹfa ti Sheikh Muhammad omo Sulaiman Al-Tamimi kọ, tira naa jẹ ọlọpọlọpọ anfani ati itumọ pẹlu bose jẹ soki, Sheikh darukọ awọn ipinle nla mẹfa ti Sharia Islam mu wa ki
Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa Read More »
Share this book Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi – ﴿وَإِذۡ قَالَ مُوسَىٰ لِقَوۡمِهِۦٓ إِنَّ ٱللَّهَ يَأۡمُرُكُمۡ أَن تَذۡبَحُواْ (………..)﴾ Nígbà tí Mūsā sọ fún àwọn ènìyàn rẹ̀ pé: Dájúdájú Allāhu pa yín láṣẹ pé kí ẹ pa (………). 2- ﴿فَٱلۡتَقَمَهُ (……….) وَهُوَ مُلِيمٞ﴾ Nitorina (…….) si gbe e mi, o si
Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi Read More »