Free DownloadIwe Zakat
Iwe Zakat, Sheikh Dr. Haitham Sarhan ló kọ ọ, o ṣalaye sinu rẹ awọn ọrọ pataki tí ó nii ṣe pẹlu zakat ọranyan ati zakat ti a fẹ, ati itumọ zakat, ati awọn owo ti zakat jẹ ọranyan ninu wọn, ati awọn ti wọ́n ní ẹtọ si zakat ti a sì maa sán fun wọn,…


