
Tani awa?
من نحن؟ Ede Yoruba Tani awa? Awa ni Musulumi ti a njọsin fun Ọlọhun nikan ṣoṣo, ti ko si orogun fun Un, A ntẹle Al-Qur’an

من نحن؟ Ede Yoruba Tani awa? Awa ni Musulumi ti a njọsin fun Ọlọhun nikan ṣoṣo, ti ko si orogun fun Un, A ntẹle Al-Qur’an

زكاة الفطر اللغة يوربا Yiyo jakaa odun itunu aawe Ede Yoruba #YiyoJakaaOdunItunuAawe #JakaaNiYoruba #IsinIslamNiYoruba #EkoIslam #MusulumiYoruba

خلاصة من الخلاصة في علوم القرآن اللغة اليوربا Ọrọ ṣoki lati inu Tira (Al-Khulaasa) ti o sọrọ nipa awọn imọ-ijinlẹ inu Al-Qur’an Alapọnle Ede Yoruba

هيا نتعلم حروف اللغة العربية مع الحركات O yaa ẹ jẹ ki a kọ imọ nipa awọn alfabẹti ede Larubawa pẹlu awọn àmìn wọn أرسم

Iwe aawẹ, Sheikh Dr. Haitham Sarhan ló kọ ọ, o ṣalaye sinu rẹ awọn ọrọ pataki tí ó nii ṣe pẹlu aawẹ ọranyan ati aawẹ

Iwe Zakat, Sheikh Dr. Haitham Sarhan ló kọ ọ, o ṣalaye sinu rẹ awọn ọrọ pataki tí ó nii ṣe pẹlu zakat ọranyan ati zakat

# Ọjọ iṣẹgun ni ọjọ Ashura ninu oṣu Muharram 16/7/2024 # Ọlá ti nbẹ fun un: O ma pa ẹṣẹ ọdun tí ó kọja rẹ́

Awọn oru mẹwa Oun ni awọn oru oṣu Dhul-Hijjah Kini a fẹ fi pade awọn ọjọ wọnyi? Lati ọdọ Ibnu Abbas, o sọpe: Anabi –

دليل المسلم الجديد . ما هو الإسلام؟ Itọsọna Musulumi tuntun. Kini Islam? Èdè Yorùbá. اللغة يوربا

لماذا لا نحتفل برأس السنة الميلادية لغة يوربا. Kilode ti aase gbodo bawon se odun ibere odun keresi. Ede Yoruba.
11 يوربا Èdè Yorùbá ?? Islam – Aye ẹkọ SunnahLabẹ amojuto Dọkita Haitham Sarhan
اللغة يوربا
Èdè Yorùbá
YouTube
Telegram
https://t.me/nigerian0
?https://sarhaan.com/a/%d9%8a%d9%88%d8%b1%d9%88%d8%a8%d8%a7-yoroba/
site
https://alsarhaan.com/yrb
لغة يُورُبا هي لغة تستخدم جنوب الصحراء الكبرى. تعد اللغة الأم بالنسبة لشعب يوربا، وهي لغة رسمية في نيجيريا. تستخدم في نيجيريا، وبنين، وتوغو، وسيراليون. كما تستخدمها بعض الجاليات في البرازيل، المعروفين هناك باسم “Lukumi”، وفي كوبا (من قبل جالية “Nago”). تعتبر اللغة من اللغات البنوية الكونغولية المتفرعة من العائلة اللغوية النيجيرية الكونغولية. يستخدمها اليوم أكثر من 20 مليون شخص. وهي لغة نغمية.