Aprender a caligrafia árabe a caligrafia do nobre Al- Qur_an
Ọrọ soki nipa iwe naa. Kikọ nipa bi asen kọ Larubawa ati Juzhu A'mma inu Al-Qur’an Alapọnle: Iwe kan ni, tia kọ ni ede yoruba, ti Dokita Haitham Sarhan se, ogbero lati kọwa ni bi asen fi ọwọ kọ larubawa nipasẹ bibẹrẹ pẹlu kiko awọn lẹta ati isesi wọn loriṣiriṣi, lẹhinna okọwa bi asen lo lori diẹ ninu awọn ọrọ imọ-ijinlẹ, bakanna ogbero lati kọwa bi asen kọ larubawa Uthmany- eyiti o jẹ larubawa ti afi kọ Al-Qur'an ni akoko Uthman, ki...
Aprender a caligrafia árabe a caligrafia do nobre Al- Qur_an
Ọrọ soki nipa iwe naa.
Kikọ nipa bi asen kọ Larubawa ati Juzhu A'mma inu Al-Qur’an Alapọnle:
Iwe kan ni, tia kọ ni ede yoruba, ti Dokita Haitham Sarhan se, ogbero lati kọwa ni bi asen fi ọwọ kọ larubawa nipasẹ bibẹrẹ pẹlu kiko awọn lẹta ati isesi wọn loriṣiriṣi, lẹhinna okọwa bi asen lo lori diẹ ninu awọn ọrọ imọ-ijinlẹ, bakanna ogbero lati kọwa bi asen kọ larubawa Uthmany- eyiti o jẹ larubawa ti afi kọ Al-Qur'an ni akoko Uthman, ki Ọlọhun bawa yọnu si - nipasẹ lilo lori Juzhu Amma. Iwe kan ni todun tosi fani mọra, o dara fun ọmọde ati agba, ati awọn tonsọ larubawa abinibi ati awọn ti kii ṣe larubawa abinibi.
Aprender a caligrafia árabe a caligrafia do nobre Al- Qur_an
Scan QR Code | Use a QR Code Scanner to fast download directly to your mobile device