![](https://sarhaan.com/wp-content/uploads/2022/12/%D9%87%D9%8A%D8%A7-%D8%A8%D9%86%D8%A7-%D9%86%D8%AA%D8%B9%D9%84%D9%85-%D9%8A%D9%88%D8%B1%D9%88%D8%A8%D8%A7.png)
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́: Ìwé kan ní èdè Yorùbá, tí Dókítà Haitham Sarhan kọ, ní èrò láti kọ́ ọmọ Mùsùlùmí ní àwọn ofin ẹ̀sìn, ìwà àti ẹkọ Islam, lọna todun, tíó fani mọ́ra, Awọn ọrọ inu ẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé, osi lọ ni ìlànà òfin sharia, pẹlu sise akiyesi ifẹ ọmọde fun ere idaraya ati awọn nkan tio fani mọra. هيا بنا نتعلم: كتاب بلغة يوروبا، ألفه الدكتور هيثم سرحان،...
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́: Ìwé kan ní èdè Yorùbá, tí Dókítà Haitham Sarhan kọ, ní èrò láti kọ́ ọmọ Mùsùlùmí ní àwọn ofin ẹ̀sìn, ìwà àti ẹkọ Islam, lọna todun, tíó fani mọ́ra, Awọn ọrọ inu ẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé, osi lọ ni ìlànà òfin sharia, pẹlu sise akiyesi ifẹ ọmọde fun ere idaraya ati awọn nkan tio fani mọra.
هيا بنا نتعلم: كتاب بلغة يوروبا، ألفه الدكتور هيثم سرحان، يهدف إلى تعليم الطفل المسلم مبادئ الدين والأخلاق والآداب الإسلامية من خلال أسلوب ممتع وشيق، جمع بين موثوقية المعلومة والالتزام بالضوابط الشرعية وبين مراعاة حب الطفل لِلَّعب والتسلية والتشويق.
المستوى الأول
Ipele alakọkọ
هيا بنا نتعلم
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́
لغة يوروبا
Èdè Yorùbá
المؤلف د هيثم سرحان
Onkọwe ni Dọkita Haitham Sarhan
المدرس بالمسجد النبوي سابقا، والمشرف على معهد السنة
Olukọ ni tẹlẹ ni Mosalasi Anabi, oun sini alamojuto ile-ẹkọ Sunnah.
حقوق الطبع والنشر متاحة للجميع
Ẹtọ titẹ ati pinpin owa fun gbogbo eniyan-
Oya ẹjẹ ká kẹ́kọ̀ọ́
Scan QR Code | Use a QR Code Scanner to fast download directly to your mobile device