Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa
Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa: Iwe kan ni, ni Ede Yoruba ti Dokita Haitham Sarhan kọ, o ṣe alaye tira Awọn ipinlẹ mẹfa ti Sheikh Muhammad omo Sulaiman Al-Tamimi kọ, tira naa jẹ ọlọpọlọpọ anfani ati itumọ pẹlu bose jẹ soki, Sheikh darukọ awọn ipinle nla mẹfa ti Sharia Islam mu wa ki ẹsin ati aiye le duro daada, o si ṣe alaye wọn daada, ṣugbọn peluẹ ọpọlọpọ awọn ọlọgbọn aiye ṣe aṣiṣe ninu rẹ …. Olusalaye iwe yi ṣe ni awọn...
Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa
Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa: Iwe kan ni, ni Ede Yoruba ti Dokita Haitham Sarhan kọ, o ṣe alaye tira Awọn ipinlẹ mẹfa ti Sheikh Muhammad omo Sulaiman Al-Tamimi kọ, tira naa jẹ ọlọpọlọpọ anfani ati itumọ pẹlu bose jẹ soki, Sheikh darukọ awọn ipinle nla mẹfa ti Sharia Islam mu wa ki ẹsin ati aiye le duro daada, o si ṣe alaye wọn daada, ṣugbọn peluẹ ọpọlọpọ awọn ọlọgbọn aiye ṣe aṣiṣe ninu rẹ ….
Olusalaye iwe yi ṣe ni awọn tabili ati ipin ipin kole ranrun lati ha sori, lẹni tin sọ erogba onkọwe nibi sise iwe naa ni fufuyẹ ati irọrun.
شرح الأصول الستة: كتاب بلغة يوروبا من تأليف الدكتور هيثم سرحان، يشرح فيه رسالة الأصول الستة للشيخ محمد بن سليمان التميمي، وهي رسالة كثيرة الفوائد وعظيمة المعاني مع اختصارها، ذكر فيها الشيخ ستة أصول عظيمة جاءت بها الشريعة الإسلامية من أجل استقامة الدين والدنيا معًا، وبينتها بيانًا واضحًا بينًا ولكن مع ذلك غلط فيها كثير من أذكياء العالم..
جعلها الشارح على شكل جداول وتقسيمات تسيهلًا للحفظ وتيسيرًا للضبط مراعيًا فيها مقصد المؤلف من حيث سهولة العبارة واختصارها.
Alaye
Awọn ipinlẹ mẹfa
شَرْحُ
الْأُصُولِ السِّتَّةِ
Ti Sheikh Al-Islam:
Muhammad ọmọ Abdul-Wahhab ọmọ Sulaiman Attamimi kọ (ki Olọhun bawa kẹ(
Olusalaye ni:
Haitham ọmọ Muhammad Sarhan
Olukọni ni ile-ẹkọ Al-Haram ni Mossalassi Anabi - tẹlẹ - ati alamojuto ile-ẹkọ Sunnah
mahadsunnah.com
غفر الله له ولوالديه ولمن أعانه على إخراج هذا الكتاب
Ki Olorun dariji, ati awọn obi rẹ, ati gbogbo eniti ti o ran lọwọ lati gbe iwe yii jade
Alaye Awọn ipinlẹ mẹfa
Scan QR Code | Use a QR Code Scanner to fast download directly to your mobile device