”
#3756HadeethEnc[O ni alaafia]
Lati ọdọ Abu Hurayra - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Mo gbọ ti ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - n sọ pe: «Gbogbo ijọ mi ni wọn maa ṣọ kuro nibi aburu ayaafi awọn alaṣehan, ati pe dajudaju ninu aṣehan ni ki ọmọnìyàn o ṣe iṣẹ kan ni oru, lẹyin naa ki o wa…
”
#3777HadeethEnc[O ni alaafia]
Lati ọdọ Abu Hurayrah - ki Ọlọhun yọnu si i - lati ọdọ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - o sọ pe: "ẹru kan ko ni se ibasiri fún ẹrú kan láyé nbi ayaafi ki Ọlọhun se ibasiri fún un ni ọjọ igbende".
”
#3779HadeethEnc[O ni alaafia]
Lati ọdọ Jaabir - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: mo gbọ tí Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - sọ ni ọdun mẹta síwaju koto fi ayé silẹ báyi pé: "Ẹnikan ninu yin ko gbọ ku ayaafi ki o ni àbá daada si Ọlọhun".
”
#3863HadeethEnc[O ni alaafia]
Láti ọdọ Abu Hurayrah kí Ọlọhun yọnu si: Dájúdájú arakunrin kan sọ pé: irẹ ojisẹ Ọlọhun mo ni awọn ẹni tí mo nso okun ẹbi wọn pọ ti awọn si nja kuro lọdọ mi, mo nṣe daada si wọn bẹẹ ni wọn se àìda si mi, mo nṣe suuru pẹlu wọn bẹẹ ni wọn wù iwa aimọkan pẹlu mi, Anọbi sọ…
”
#3910HadeethEnc[O ni alaafia]
”
#4177HadeethEnc[O ni alaafia]
Láti ọdọ baba Musa - kí Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) sọ pe: "Àpèjúwe ẹniti nrántí Olúwa rẹ ati ẹnití kò rántí Olúwa rẹ da gege bi alààyè ati òkú ni ", gbólóhùn ti Muslim ni" Àpèjúwe ile ti wọn ti nranti Ọlọhun, ati ile ti wọn kò…
”
#4180HadeethEnc[O ni alaafia]
Láti ọdọ bàbá Sa'eed Al-Khudriy ki Ọlọhun yọnu si: Dájúdájú Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) o joko ni ọjọ kan lórí minbari ti awa si joko ní ẹgbẹ rẹ, ló bá sọ pé: "dájúdájú ninu nkan ti emi nbẹru fún nípa yin ti mo bá lọ tán ni yodoyindin aye àti ọsọ rẹ ti wọn…
”
#4243HadeethEnc[O ni alaafia]
Lati ọdọ Abu Hurairah - ki Ọlọhun yọnu si i - ó ṣo pé: Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pe: «Ẹni ti o n gun nkan ni o maa salamọ si ẹni ti o n rin, ẹni ti o n rin ni o máa salamọ si ẹni ti o jokoo, awọn ti onka wọn kere ni wọ́n maa salamọ si awọn ti…
”
#4302HadeethEnc[قال الترمذي: حديث حسن]
Láti ọdọ Abu Dhari, tii ṣe Jundub ọmọ Junaadah, àti Abu Abdir-Rahman, tii ṣe Mu'ahdh ọmọ Jabal kí Ọlọhun yọnu sí awọn méjèjì, láti ọdọ òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ Ọlọhun àti ọla Rẹ o máa ba a, o sọ pé: «Bẹrù Ọlọhun ní ibikibi tí o ba wa, tẹ̀lé ìṣe búburú pẹ̀lú ìṣe rere, yóò pa…
”
#4304HadeethEnc[O ni alaafia]
Láti ọ̀dọ̀ Abu Bakrah- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Mo gbọ ti ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé: “Ti Mùsùlùmí méjì ba pàdé ara wọn pẹ̀lú idà, ati ẹni ti o pa eeyan ati ẹni tí wọ́n pa, wọn jọ maa wọ iná ni”, mo wa sọ pe: Irẹ ojiṣẹ Ọlọhun, a gbọ ti…
”
#4308HadeethEnc[O ni alaafia]
Lati ọdọ An-nawwaas ọmọ Sim'aan al-ansaariy - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Mo beere lọwọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) nípa iṣẹ daada ati iwa ẹṣẹ, lo bá sọ pé: "daada ni iwa daada, ẹṣẹ ni nkan ti nlọ ti mbọ ninu igbaaya rẹ, ti kò sì wù ọ ki awọn eniyan mọn…
”
#4314HadeethEnc[O ni alaafia]
Láti ọ̀dọ̀ An-Nuhmaan ọmọ Basheer- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pé: Mo gbọ lẹ́nu ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o n sọ pe- An-Nuhmaan wa na ìka rẹ méjèèjì si etí rẹ méjèèjì-: “Dajudaju nǹkan ẹtọ fi ojú hàn, dájúdájú nǹkan eewọ naa fi ojú hàn, o wa n bẹ…