tó bá ṣe pé bí o se wà lo sọ yii, bi ẹni pe ìwà wọn ti su ọ bayii, ikun lọwọ Ọlọhun konii ye konii gbo fun ọ lori wọn lópin igbati o ba ti wà bẹẹ
Láti ọdọ Abu Hurayrah kí Ọlọhun yọnu si: Dájúdájú arakunrin kan sọ pé: irẹ ojisẹ Ọlọhun mo ni awọn ẹni tí mo nso okun ẹbi wọn pọ ti awọn si nja kuro lọdọ mi, mo nṣe daada si wọn bẹẹ ni wọn se àìda si mi, mo nṣe suuru pẹlu wọn bẹẹ ni wọn wù iwa aimọkan pẹlu mi, Anọbi sọ…

