Àpèjúwe ẹniti nrántí Olúwa rẹ ati ẹnití kò rántí Olúwa rẹ da gege bi alààyè ati òkú ni
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Láti ọdọ baba Musa - kí Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) sọ pe: "Àpèjúwe ẹniti nrántí Olúwa rẹ ati ẹnití kò rántí Olúwa rẹ da gege bi alààyè ati òkú ni ", gbólóhùn ti Muslim ni" Àpèjúwe ile ti wọn ti nranti Ọlọhun, ati ile ti wọn kò rántí Ọlọhun níbẹ o da gẹgẹ bí alaayè ati òkú ".
Explanation
Bẹẹ náà ni ilé wan royin rẹ pẹlu isemi (aláayè) ti awan olùgbé rẹ bá nranti Ọlọhun, ti wan ba rántí Ọlọhun a jẹ pé òkú ni ile náà kúrò níbi ìrántí Ọlọhun, ti wan ba lo aláayè ati òkú lati fí royin ile ẹni ti o gbe bẹ ni wan fi ọrọ bawo.
Benefits
Ìrántí ni isemi emi bẹẹ ni emi ni isemi ará.
Ninu imọna ati ìlànà Anọbi ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má ba ni lílò òwe tabi àkàwé lati mu ìtumọ ọrọ Simoni.
An-Nawawi sọ pé: fifẹ ki a má darukọ Ọlọhun ti o ga jùlọ ninu ile wà níbẹ̀, ati pe ilé ko gbọdọ pa ṣofo ní bi ìrántí ati idaruko Ọlọhun.
An-Nawawiy sọ pé: o wa ninu hadith náà pé gígùn ẹmi lórí itẹle aṣẹ Ọlọhun ohun ti o lọ lá ni bo tilẹ jẹ pé òkú ngbé rà lọsí bi tó lòó rè ni, nítorípé aláayè na yóò padà ló dára pọ mọ ti yóò lè kun jù lọ latara awon iṣẹ itẹle aṣẹ Ọlọhun ti o ti se.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

