“Maa wa nibi adágún naa ki n le ri ẹni tí o maa wa si ọdọ mi ninu yin, wọn maa mu awọn èèyàn kan kúrò ni tòsí ọdọ mi, mo maa wa sọ pé: Irẹ Oluwa mi, ara ìjọ mi ni wọn
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Asma ọmọ Abubakr, ki Ọlọhun yọnu si àwọn mejeeji, o sọ pe: Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, wí pé: “Maa wa nibi adágún naa ki n le ri ẹni tí o maa wa si ọdọ mi ninu yin, wọn maa mu awọn èèyàn kan kúrò ni tòsí ọdọ mi, mo maa wa sọ pé: Irẹ Oluwa mi, ara ìjọ mi ni wọn, wọn maa wa sọ pé: Ǹjẹ́ o mọ nǹkan ti wọn ṣe lẹ́yìn rẹ, mo fi Ọlọhun bura, wọn kò yẹ̀ wọn kò gbò ti wọn n kúrò nínú Isilaamu”.
Explanation
Benefits
Ewu ìyapa ohun ti Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- wa lórí rẹ.
Igbaniyanju lati di sunna Anabi mu, ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

