Awọn iwa Musulumi
اخلاق المسلم Awọn iwa Musulumi اسم اللغة يوروبا Yoruba و لا تعتدوا. E ma ṣe tayọ ala و لا تعثوا في الأرض مفسدين. E ma ṣe ibajẹ lori ilẹ. و لا تلبسوا الحق بالباطل E ma ṣe da irọ pọ mọ otitọ. و لا تقف ما ليس لك به علم Ma tẹle ohun ti o ni imọ nipa ẹ و لا تمش في الأرض مرحا Má rìn irin igberaga lórí ilẹ̀ و لا تصعر خدك للناس Má ṣe yí ẹ̀kẹ́...
Awọn iwa Musulumi
اخلاق المسلم
Awọn iwa Musulumi
اسم اللغة
يوروبا
Yoruba
و لا تعتدوا.
E ma ṣe tayọ ala
و لا تعثوا في الأرض مفسدين.
E ma ṣe ibajẹ lori ilẹ.
و لا تلبسوا الحق بالباطل
E ma ṣe da irọ pọ mọ otitọ.
و لا تقف ما ليس لك به علم
Ma tẹle ohun ti o ni imọ nipa ẹ
و لا تمش في الأرض مرحا
Má rìn irin igberaga lórí ilẹ̀
و لا تصعر خدك للناس
Má ṣe yí ẹ̀kẹ́ rẹ sí àwọn ènìyàn
و اخفض جناحك للمؤمنين.
Ni itẹriba fun awọn onigbagbọ ododo.
و اغضض من صوتك
Rẹ ohun rẹ nlẹ
و اقصد في مشيك.
Rin lọna iwọntuwọnsi
و اعرض عن الجاهلين.
ṣẹri kuro lọdọ awọn alaimọkan
خذ العفو و أمر بالعرف.
ṣe amojukuro ki o si paṣẹ iwa daada
ادفع بالتي هي أحسن.
Fi iwa daada ti iwa bu lọ
ادع إلى سبيل ربك بالحكمة
pèpè sí ọ̀nà Olúwa rẹ pẹ̀lú ọgbọ́n
لا تبطلوا صدقاتكم بالمن و الأذى
Ẹ ma ṣe ba saara yin jẹ pẹlu iregun ati ipalara
و لا تأكلوا أموالكم بينكم بالباطل
Ẹ ma ṣe jẹ owo ara yin pelu ibajẹ
و لا تنابزوا بالألقاب.
Ẹ ma ṣe pe ra yin ni orukọ ti koda
و لا يسخر قوم من قوم
Ki awọn ènìyàn kan maṣe fi awọn ènìyàn kan ṣe yẹ̀yẹ́
و لا يغتب بعضكم بعضا
Ẹ má sọ̀rọ̀ ara yín lẹyin
و لا تجسسوا.
Ẹ má tọpinpin ara yín
إجتنبوا كثيرا من الظن
Ẹ jina si pupọ abadida
ادخلوا في السلم كافة
Ẹ wọ inu ẹsin yanyan
و إذا حييتم بتحية فحيوا بأحسن منها
Bí wọn a bá kí yín, ẹ kí wọn pẹlu eyi to dára jùlọ
و بالوالدين إحسانا و ذي القربى و اليتامى
Ẹ ṣe daada si awọn obi yin, ati awọn to sun mọ yin ati awọn ọmọ orukan
و أطعموا البائس الفقير
Ẹ fun àwọn aláìní ni ounjẹ
و لا تتبدلوا الخبيث بالطيب
Ẹ má fi nkan daada ṣe pàṣípààrọ̀ ohun búburú
و آتوا اليتامى أموالهم
Ẹ fún àwọn ọmọ òrukàn ní owó wọn
أنفقوا مما رزقناكم
Ẹ na ninu ohun ti A fun nyin
و قولوا قولا سديدا
Ẹ sọ ọrọ ti o tọ
و قولوا للناس حسنا
Ẹ sọ ọrọ daada fun àwọn eniyan
و لا تعاونوا على الإثم و العدوان
Ẹ ma ṣe fọwọsowọpọ lori ẹṣẹ ati ikọja ala
و تعاونوا على البر و التقوى
Ẹ fi ọwọsowọpọ lori daada ati ibẹru Olohun
و احفظوا أيمانكم
Ẹ mu ibura yin ṣẹ
و أوفوا بعهد الله إذا عاهدتم
Ẹ mu adehun Ọlọrun ṣẹ nigbati ẹ ba ṣe adehun
و أوفوا الكيل إذا كلتم
Ẹ pe oṣuwọn nigbati ẹ ba nwọn
و زنوا بالقسطاس المستقيم
Ẹ wọn pẹ̀lú òṣùwọ̀n to dọgba
كونوا قوامين بالقسط
Ẹ jẹ oluduro sinsin pẹlu deede
اعدلوا
Ẹ ṣe deede
Awọn iwa Musulumi
Scan QR Code | Use a QR Code Scanner to fast download directly to your mobile device