Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi
Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi - ﴿وَإِذۡ قَالَ مُوسَىٰ لِقَوۡمِهِۦٓ إِنَّ ٱللَّهَ يَأۡمُرُكُمۡ أَن تَذۡبَحُواْ (...........)﴾ Nígbà tí Mūsā sọ fún àwọn ènìyàn rẹ̀ pé: Dájúdájú Allāhu pa yín láṣẹ pé kí ẹ pa (………). 2- ﴿فَٱلۡتَقَمَهُ (..........) وَهُوَ مُلِيمٞ﴾ Nitorina (…….) si gbe e mi, o si di ẹni ibawi. 3- ﴿وَتَفَقَّدَ ٱلطَّيۡرَ...
Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi
Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi
- ﴿وَإِذۡ قَالَ مُوسَىٰ لِقَوۡمِهِۦٓ إِنَّ ٱللَّهَ يَأۡمُرُكُمۡ أَن تَذۡبَحُواْ (...........)﴾
Nígbà tí Mūsā sọ fún àwọn ènìyàn rẹ̀ pé: Dájúdájú Allāhu pa yín láṣẹ pé kí ẹ pa (………).
2- ﴿فَٱلۡتَقَمَهُ (..........) وَهُوَ مُلِيمٞ﴾
Nitorina (…….) si gbe e mi, o si di ẹni ibawi.
3- ﴿وَتَفَقَّدَ ٱلطَّيۡرَ فَقَالَ مَا لِيَ لَآ أَرَى (...........) أَمۡ كَانَ مِنَ ٱلۡغَآئِبِينَ﴾
O se abẹwo awọn eye na, o si wipe: Kilode ti emi ko ri (..........) abi o jẹ ọkan ninu awọn ti ko wa ni?
4- ﴿فَبَعَثَ ٱللَّهُ (..........) يَبۡحَثُ فِي ٱلۡأَرۡضِ لِيُرِيَهُۥ كَيۡفَ يُوَٰرِي سَوۡءَةَ أَخِيهِۚ﴾
Ọlọ́run rán (..........) láti wá ilẹ̀, láti fi hàn bí ó ṣe bo ihoho oku ọmọ-iya rẹ̀.
5- ﴿قَالَ إِنِّي لَيَحۡزُنُنِيٓ أَن تَذۡهَبُواْ بِهِۦ وَأَخَافُ أَن يَأۡكُلَهُ (..........) وَأَنتُمۡ عَنۡهُ غَٰفِلُونَ﴾
O sope: Dajudaju yio dun mi ti ẹ ba mu u lọ, atipe emi n bẹru pe (..........) yio pa a jẹ nigbati ẹẹ ba ṣe akiyesi rẹ.
6- ﴿يَٰٓأَيُّهَا (..........) ٱدۡخُلُواْ مَسَٰكِنَكُمۡ لَا يَحۡطِمَنَّكُمۡ سُلَيۡمَٰنُ وَجُنُودُهُۥ وَهُمۡ لَا يَشۡعُرُونَ﴾
Eyin (..........)ẹ wọ inu awọn ibugbe yin o, ki Sulaimana ati awọn ọmọ ogun rẹ ma ba tẹ yin pa, wọn ko si ni mọ.
7- ﴿إِنَّ هَٰذَآ أَخِي لَهُۥ تِسۡعٞ وَتِسۡعُونَ (.........) وَلِيَ (.........) وَٰحِدَةٞ ﴾
Dajudaju eyi ni arakunrin mi, o ni (……..) mọkandinlọgọrun, emi si ni (........) kanṣoṣo.
8- ﴿فَمَثَلُهُۥ كَمَثَلِ (.........) إِن تَحۡمِلۡ عَلَيۡهِ يَلۡهَثۡ أَوۡ تَتۡرُكۡهُ يَلۡهَثۚ ﴾
Apejuwe rẹ dabi (.........) ti o ba le siwaju, yio yọ ahọn sita, ti o ba si fi silẹ yio yọ ahọn.
9- ﴿أَلَمۡ تَرَ كَيۡفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصۡحَٰبِ (.........)﴾
Njẹ irẹ ko ri bi Oluwa rẹ ti ṣe pẹlu awọn ijọ (........)?
10- ﴿كَأَنَّهُمۡ (.........) مُّسۡتَنفِرَةٞ ٥٠ فَرَّتۡ مِن (.........)﴾
Wọn dabi (........) ti jìnnìjìnnì bá, ti wọn sá fun (........)
11- ﴿فَأَلۡقَىٰ عَصَاهُ فَإِذَا هِيَ (.........) مُّبِينٞ﴾
O ju ọpá rẹ silẹ, nigbana o si di (........) to foju han.
12- ﴿مَثَلُ ٱلَّذِينَ حُمِّلُواْ ٱلتَّوۡرَىٰةَ ثُمَّ لَمۡ يَحۡمِلُوهَا كَمَثَلِ (.........) يَحۡمِلُ أَسۡفَارَۢاۚ﴾
Apẹrẹ àwọn tí a fi Tira At-Taorata ran nisẹ, tí wọn kò sì tẹle, ó dà gẹgẹbi apẹrẹ (.........) tí o gbé àwọn ìwé.
13- ﴿وَيَٰقَوۡمِ هَٰذِهِ (........) ٱللَّهِ لَكُمۡ ءَايَةٗۖ فَذَرُوهَا تَأۡكُلۡ فِيٓ أَرۡضِ ٱللَّهِۖ وَلَا تَمَسُّوهَا بِسُوٓءٖ﴾
Eyin eniyan mi, eyi ni (........) Olohun, o jẹ ami kan fun yin, nitori naa ẹ fi silẹ ki o ma jẹ kiri lori ilẹ Olohun, ki ẹ ma si fọwọ aburu kan.
14- ﴿وَأَوۡحَىٰ رَبُّكَ إِلَى (.........) أَنِ ٱتَّخِذِي مِنَ ٱلۡجِبَالِ بُيُوتٗا وَمِنَ ٱلشَّجَرِ وَمِمَّا يَعۡرِشُونَ﴾
Oluwa rẹ ransẹ si (........) pe: ki o kole si ara awọn apata ati awọn igi ati awọn ohun ti wọn mọ to ga.
15- ﴿فَأَرۡسَلۡنَا عَلَيۡهِمُ ٱلطُّوفَانَ وَ(.........) وَ(.........) وَ(.........) وَٱلدَّمَ ءَايَٰتٖ مُّفَصَّلَٰتٖ فَٱسۡتَكۡبَرُواْ وَكَانُواْ قَوۡمٗا مُّجۡرِمِينَ﴾
A rán Ìkún omi si wọn àti (........) àti (........) ati (……..) ati ẹjẹ, ni awọn ami to han, sugbọn wọn se igbéraga, wọ́n sì jẹ́ ẹlẹsẹ.
16- ﴿مَثَلُ ٱلَّذِينَ ٱتَّخَذُواْ مِن دُونِ ٱللَّهِ أَوۡلِيَآءَ كَمَثَلِ (..........) ٱتَّخَذَتۡ بَيۡتٗا﴾
Apejuwe awọn ẹniti wọn mu awọn orisa ni alatilẹhin lẹyin Olohun o dabi (..........) tọ kọ ile kan.
17- ﴿فَلَمَّا عَتَوۡاْ عَن مَّا نُهُواْ عَنۡهُ قُلۡنَا لَهُمۡ كُونُواْ (.........) خَٰسِِٔينَ﴾
Nígbà tí wọ́n se igberaga nipa ohun tí a kọ fún wọn, Awa sọ fún wọn pé ẹ di (........) ẹni yẹpẹrẹ.
18- ﴿أَفَلَا يَنظُرُونَ إِلَى (........) كَيۡفَ خُلِقَتۡ﴾
Eeṣe ti awọn ko wo (........) bi a ti ṣe da a?
19- ﴿خُشَّعًا أَبۡصَٰرُهُمۡ يَخۡرُجُونَ مِنَ ٱلۡأَجۡدَاثِ كَأَنَّهُمۡ (........) مُّنتَشِرٞ﴾
Awọn oju wọn yio yẹpẹrẹ, wọn o ma jade lati inu sare gẹgẹbi ẹnipe (........) ni wọn ti wọn fọnka.
20- ﴿يَوۡمَ يَكُونُ ٱلنَّاسُ (.........) ٱلۡمَبۡثُوثِ﴾
ọjọ́ tí àwọn ènìyàn yio da gẹgẹbi (….......) ti o tuka kiri.
21- ﴿مَن لَّعَنَهُ ٱللَّهُ وَغَضِبَ عَلَيۡهِ وَجَعَلَ مِنۡهُمُ (........) وَ(..........)﴾
Eniti Olorun ṣẹbi le, ti O si binu si, ti O si sọ ninu wọn di (........) ati (..........).
22- ﴿فَرَاغَ إِلَىٰٓ أَهۡلِهِۦ فَجَآءَ (........) سَمِينٖ﴾
O si yiju si awọn eniyan rẹ, o si de pẹlu (........) ti o lọra.
23- ﴿فَأَلۡقَىٰهَا فَإِذَا هِيَ (........) تَسۡعَىٰ﴾
O si ju silẹ, o si di (........) ti on wọ.
24- ﴿ثَمَٰنِيَةَ أَزۡوَٰجٖۖ مِّنَ (........) ٱثۡنَيۡنِ وَمِنَ (.......) ٱثۡنَيۡنِ﴾
Oriṣi mejo ni, meji-meji ninu (.........) ati ninu (.......).
25- ﴿إِنَّ ٱللَّهَ لَا يَسۡتَحۡيِۦٓ أَن يَضۡرِبَ مَثَلٗا مَّا (.........) فَمَا فَوۡقَهَا﴾
Dajudaju Ọlọ́run kì í tijú jù láti pa owe kan ti o mọ bi (........) tàbí nkan to ju u lọ.
26- ﴿قَالُواْ نَفۡقِدُ صُوَاعَ ٱلۡمَلِكِ وَلِمَن جَآءَ بِهِۦ حِمۡلُ (........) وَأَنَا۠ بِهِۦ زَعِيمٞ﴾
Wọ́n wipe: Awa ṣe afẹku igba ọba, ẹnití ó bá mu u wá yio ri onjẹ ẹru (..........) kan gba, èmi sì fi ọwọ sọya rẹ̀.
27- ﴿إِنَّهَا تَرۡمِي بِشَرَرٖ كَٱلۡقَصۡرِ ٣٢كَأَنَّهُ (.........) صُفۡرٞ﴾
On ju ẹta ina to da gẹgẹbi pẹtẹẹsi, wọn dabi (..........) alawọ iyeye.
28- ﴿قَالَ هِيَ عَصَايَ أَتَوَكَّؤُاْ عَلَيۡهَا وَأَهُشُّ بِهَا عَلَىٰ (........) وَلِيَ فِيهَا مََٔارِبُ أُخۡرَىٰ﴾
O sọpe: Opa mi ni, mo ma nsinmin le e, mo si fi nja ewe fun awọn (.........) mi, mo si ma nlo ni ọna miran.
29- ﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ تَدۡعُونَ مِن دُونِ ٱللَّهِ لَن يَخۡلُقُواْ (.........) وَلَوِ ٱجۡتَمَعُواْ لَهُ﴾
Dajudaju awọn ohun ti ẹ npe lẹyin Ọlọhun ko le da (........) koda ti wọn ba parapọ lati ṣe.
30- ﴿وَأَعِدُّواْ لَهُم مَّا ٱسۡتَطَعۡتُم مِّن قُوَّةٖ وَمِن رِّبَاطِ (......) تُرۡهِبُونَ بِهِۦ عَدُوَّ ٱللَّهِ وَعَدُوَّكُمۡ﴾
E pese ohun ija ti ẹ ba lagbara rẹ fun wọn ati ni siso (......) mọlẹ, lati dẹruba awọn ọta Ọlọrun ati ọtá yin.
Fi oruko eranko tabi eye si awon alafo wonyi
Scan QR Code | Use a QR Code Scanner to fast download directly to your mobile device