# Ọjọ iṣẹgun ni ọjọ Ashura ninu oṣu Muharram 16/7/2024

# Ọjọ iṣẹgun ni ọjọ Ashura ninu oṣu Muharram

16/7/2024

# Ọlá ti nbẹ fun un:
O ma pa ẹṣẹ ọdun tí ó kọja rẹ́
gẹgẹ bi o ti fẹsẹ rinlẹ ninu Sahih Muslim
Sunnah ni ki a gba awẹ ọjọ naa pẹlu ọjọ kẹsan
15/7/2024

Tabi ọjọ kọkanla
17/7/2024

Ede Yoruba