E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin
Láti ọdọ Anas - ki Ọlọhun yọnu si i - dájúdájú Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) sọ pé: "E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin".

