o kọ kuro nibi ẹjẹ jijẹ, o wa sọ pe: “Dajudaju ẹjẹ jijẹ o ki n mu oore wa, bi ko ṣe pe wọn maa n fi gba nnkan jade lati ọwọ ahun ni”
Lati ọdọ ọmọ Umar ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji: Lati ọdọ Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- dajudaju o kọ kuro nibi ẹjẹ jijẹ, o wa sọ pe: “Dajudaju ẹjẹ jijẹ o ki n mu oore wa, bi ko ṣe pe wọn maa n fi gba nnkan jad…

