Ṣe ki n gbe ọ dìde lori nnkan ti ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- gbe mi dìde lórí ẹ? Ma fi ère kan kan silẹ àfi ki o pa a rẹ, ma si fi sàréè ti o ga kan kan silẹ afi ki o jẹ ki o bá ilẹ̀ dọ́gba
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Abu Al-Hayyaaj Al-Asadiy, o sọ pe: Aliy ọmọ Abu Tọọlib sọ fun mi pe: Ṣe ki n gbe ọ dìde lori nnkan ti ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- gbe mi dìde lórí ẹ? Ma fi ère kan kan silẹ àfi ki o pa a rẹ, ma si fi sàréè ti o ga kan kan silẹ afi ki o jẹ ki o bá ilẹ̀ dọ́gba.
Explanation
Ki wọn si ma fi sàréè ti o ga kan kan sílẹ̀ ayafi ki wọn jẹ ki o ba ilẹ̀ dọ́gba, ki wọn si wó nǹkan ti wọn kọ́ sori ẹ, tabi ki wọn ṣe e ni nǹkan ti o maa tẹ́ pẹrẹsẹ ti ko nii ga nílẹ̀ pupọ, ṣùgbọ́n o maa ga ni odiwọn àlààfo ti o wa laarin ìka àtàǹpàkò ati ika ọmọndinrin.
Benefits
Mímú ohun buruku kuro pẹ̀lú ọwọ fun ẹni ti o ba ni àṣẹ tabi agbára lati ṣe bẹ́ẹ̀ jẹ nǹkan ti o ba sharia mu.
Ojúkòkòrò Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- lori mimu gbogbo nǹkan ti o ba n tọka si oripa àsìkò aimọkan kúrò, bíi àwọn àwòrán ati awọn ère, ati awọn nǹkan ti wọn mọ sórí sàréè.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

