Dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro aṣiṣe àti ìgba gbé fún mi nípa awan ìjọ mí àti nkán tí wan ba jẹ wàn nípa láti ṣe
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ ọmọ Abbas kí Ọlọhun yọnu sí awan méjèjì dájú daju òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá rẹ máa ba sọ pé: « Dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro aṣiṣe àti ìgba gbé fún mi nípa awan ìjọ mí àti nkán tí wan ba jẹ wàn nípa láti ṣe ».
Explanation
alaba pàdé nkàn tí o yatọ sí nkan tí o gba lérò. Ẹlẹẹkeji ni : igbagbe, òun ni kí muslim se ìrántí nkán kan , ṣugbọn kí o tún gbà gbé rẹ nigbati o fẹ se , kò sí ẹsẹ fún nípa rẹ bákan náà. Ẹlẹkẹta ni : ijeni nípa se nkán, wàn le jẹ ẹrú ( ọmọ ènìyàn) nípa láti ṣe nkan tí kò fẹ se pẹlu pé koni ìkápá láti dá ijẹnipa náà padà , nígbà náà kòní sí ẹsẹ tàbí aburú kàn kan . Pẹlu ise àkíyèsí pé dájú dájú àkòrí ọrọ Hadith ni òun tí bọ nbẹ láàrin ẹrú àti Olúwa rẹ nípa ṣíṣe nkán tí wan se leewọ , ṣugbọn gbígbé nkán tí wan páni lá sẹ jù silẹ ni ti igbagbé kò tí mú aṣẹ náà kúrò, ṣugbọn tí ìwà ọdaran kan ba tí atara ṣíṣee wa ye òun tí o jẹ ẹtọ ènìyàn kò tí bọ , gẹgẹ bí kí o se sí paayan , dandan ni kí o sanwo ìtanràn emi b, tàbí kí o sesi ba mọto jẹ dandan ni fún láti san owó ìtanràn .
Benefits
Ọlá Ọlọhun lórí anọbi Muhammad kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba àti ijọ rẹ.
Gbígbé ẹsẹ kúrò kò túmọ sí pé gbígbé ìdájọ kúrò tàbí
Majẹmu ní láti wa fún gbígbé ese kúrò fún ní latara ijẹni nípa, bíi kìí ẹni tí wan jẹ nípa ni ìkápá láti ṣe nkán tí wan fí se idẹruba fún .
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

