Ko si akoran, ko si si ifi ẹyẹ fura mọ daadaa tabi aburu, ati pe mo fẹ́ràn fah'lu, o sọ pe wọn sọ pe: Kí ni fah'lu? O sọ pe: "Ọrọ ti o daa
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Anas ọmọ Maalik- ki Ọlọhun yọnu si i- lati ọdọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe: "Ko si akoran, ko si si ifi ẹyẹ fura mọ daadaa tabi aburu, ati pe mo fẹ́ràn fah'lu, o sọ pe wọn sọ pe: Kí ni fah'lu? O sọ pe: "Ọrọ ti o daa".
Explanation
Benefits
Kikọ kuro nibi ifi ẹyẹ fura mọ daadaa tabi aburu, ati pe oun ni nnkan ti wọn maa n fura mọ aburu latara rẹ, ti o si maa n ṣẹri ẹni kúrò nibi iṣẹ.
Ifuramọ idunnu ko ki n ṣe ara ifi ẹyẹ furamọ daadaa tabi aburu ti a kọ kuro nibẹ, bi ko ṣe pe o wa ninu nini ero daadaa pẹlu Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga-.
Gbogbo nnkan maa n ṣẹlẹ̀ pẹlu kadara Ọlọhun- Alagbara ti O gbọnngbọn- ni Oun nikan ṣoṣo ti ko si orogun fun Un.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

