Apejuwe bi Anabi sen kirun, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa: Aworan rẹ ni ede Yoruba
Sheikh Dr. Haitham Sarhan lo pese rẹ, On bẹ ninu ẹ, ọrọ ṣoki nipa apejuwe bi Anabi sen kirun, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa, lati ibi kabara titi de ibi salamọ, gẹgẹ bi ẹnipe onri Anabi ni, pẹlu awọn aworan alapejuwe.
صفة صلاة النبي صلى الله عليه وسلم: لوحة مصورة باللغة اليوربا
من إعداد فضيلة الشيخ الدكتور هيثم سرحان، فيها ملخص صفة صلاة النبي صلى الله عليه وسلم من التكبير إلى التسليم كأنك تراها مع الصور التوضيحية.