Bawo ni mo şe ma wo inu esin Islam

FileAction
Bawo ni mo şe ma wo inu esin IslamDownload
Bawo ni mo şe ma wo inu esin IslamDownload
Bawo ni mo şe ma wo inu esin IslamDownload

(Bawo ni mo ṣe ma wọ inu ẹsin Islam): Awọn iwe imọ to tẹlerawọn lati ọwọ Dọkita Haitham Sarhan, o sọ awọn idajọ sharia pataki ni irisi ibeere ati idahun.
Ninu abala eleyi, o sọrọ lori wiwọnu ẹsin Islam, atipe bawo ni eniyan ṣe le di Musulumi? Kini o yẹ ki o ṣe lẹyin ti o ba ti wọnu Islam tan? Ati awọn ohun pataki ti Musulumi titun nilo lati kọ ẹkọ Islam diẹdiẹ.