Free DownloadAwọn ipin işe Olohun lokan
Awọn ipin işe Olohun lokan Iwe pelebe Tawheed: Iwe kan ni ti a kọ ni ede Yoruba, ti Sheikh Dọkita Haitham Sarhan ti pese rẹ silẹ, ti o safihan awọn ẹka mẹta ti Tawheed pin si, pẹlu itumọ ikọọkan ninu wọn, ati awọn ipele ẹsin Islam, pẹlu alaye awọn origun ikọọkan ninu wọn, ati awọn…


