Free DownloadBawo ni mo şe ma wo inu esin Islam
(Bawo ni mo ṣe ma wọ inu ẹsin Islam): Awọn iwe imọ to tẹlerawọn lati ọwọ Dọkita Haitham Sarhan, o sọ awọn idajọ sharia pataki ni irisi ibeere ati idahun. Ninu abala eleyi, o sọrọ lori wiwọnu ẹsin Islam, atipe bawo ni eniyan ṣe le di Musulumi? Kini o yẹ ki o ṣe lẹyin ti…


