Fi wọn silẹ, nitori pe dajudaju mo ti mejeeji bọ ọ ni mimọ ni
Lati ọdọ Al-Mughiirah - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe. Mo wa pẹlu Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ni irin-ajo kan, ni mọ ba bẹrẹ lati bọ abọsẹsẹ alawọ rẹ mejeeji, ni o wa sọ pe: «Fi wọn silẹ, nitori pe dajudaju mo ti mejeeji bọ ọ ni mimọ ni» ni o wa fi ọwọ pa m…

