Ẹnikẹni ti o bá dun mọ ki Ọlọhun koo yọ nibi ìbànújẹ ọjọ igbende ko yaa se ìgbà láàyè fún ẹni tí ara ni lati san gbèsè tabi ko yá yaafi gbèsè náà fun
Láti ọdọ bàbá Qataada - ki Ọlọhun yọnu si - o ni oun wá ẹni tó jẹ oun lówó, o wa fi ara pamọ fún òun lẹyìn náà òun padà rí i, ni o wa sọ pé: oun wa ninu ìṣòro lati sanwo rẹ, ni o wá ṣọ pe: se o le fi orukọ Ọlọhun búra? o sọ pe: se o le fi orukọ Ọlọhun búra? o sọ pé: dáj…

