ẹ má ṣe bú atẹgun , yi e bá rí nkankan ti ko wù yín e sọ bayi pe: " irẹ Ọlọhun àwa n'bere òòrè ti wà lára atẹgun yí lọdọ rẹ àti oore tó wà nínú rẹ àti oore nkan ti wan pàá lasẹ, anwa idaabobo lọdọ rẹ níbi aburú afẹfẹ yí ati aburú nkan ti wa nínú rẹ ati aburú nkan ti wan pàá lasẹ,
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Láti ọdọ Ubayy ọmọ Kahab ki Ọlọhun yọnu sí o sọ pé : òjíṣẹ Ọlọhun ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa bá sọ pé : b " ẹ má ṣe bú atẹgun , yi e bá rí nkankan ti ko wù yín e sọ bayi pe: " irẹ Ọlọhun àwa n'bere òòrè ti wà lára atẹgun yí lọdọ rẹ àti oore tó wà nínú rẹ àti oore nkan ti wan pàá lasẹ, anwa idaabobo lọdọ rẹ níbi aburú afẹfẹ yí ati aburú nkan ti wa nínú rẹ ati aburú nkan ti wan pàá lasẹ,
Explanation
Benefits
Iṣẹ r padà sí ọdọ Ọlọhun àti ìwà ìdáàbòbò pẹlu Rẹ̀ níbi aburú nikan toda.
Atégùn le jẹ òun tí wan pa lasẹ òòrè bẹ ni wan le pa lasẹ àìdá.
Ọmọ Baz sọ pé : bibu atégùn wa nínú awan apapọ ìyapa Ọlọhun , nítorí pé ẹdá tí wan pá lasẹ ní wan a fí òòrè ran bẹni wan a fí aburú ran , kò lẹtọ kí a bù , a gbọdọ sọ pé : kí Ọlọhun ṣebi lè atégùn, tàbí Ọlọhun yóò kọ atẹgun , tàbí Ọlọhun kòní fí alubarika sí atẹgun yí , tàbí inkan to ba farajọ bẹ , ṣugbọn musulumi ni láti ṣe nkán tí anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà tọ sí ojú ònà rẹ.
A o tun fi wan atégùn nípa ṣíṣe eebu leewọ àti ìbáwí awan nkán tí ọ rọ mọ ooru, àti òtútù àti orún àti eruku àti àwọn nkán mí nínú awan ẹdá Ọlọhun àti ìdarí rẹ.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

