Irẹ ọmọdekunrin yii, darukọ Ọlọhun, ki o si jẹun pẹlu ọwọ ọtun rẹ, ki o si tun jẹ ninu nkan ti o sunmọ ọ
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Umar ọmọ Abu Salama- ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Mo jẹ ọmọdekunrin ni abẹ itọju Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ati pe ọwọ mi o si duro si oju kan ninu abọ, ni Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa sọ fun mi pé: «Irẹ ọmọdekunrin yii, darukọ Ọlọhun, ki o si jẹun pẹlu ọwọ ọtun rẹ, ki o si tun jẹ ninu nkan ti o sunmọ ọ»
Ìyẹn o wa yẹ ni ìṣesí ounjẹ mii lẹyin igba naa.
Explanation
Alakọkọọ rẹ ni: Gbólóhùn "BismilLah" ni ibẹrẹ ounjẹ.
Ati pe ẹlẹẹkeji ni: jíjẹ ounjẹ pẹlu ọwọ ọtun.
Ati pe ẹlẹẹkẹta rẹ ni: Jijẹ nibi ẹgbẹ ti o ba sunmọ ọn ninu oúnjẹ.
Benefits
Kikọ awọn ọmọde ni awọn ẹkọ, agaga julọ ẹni ti o ba wa ni abẹ itọju eeyan.
Ṣiṣe idẹkun Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a -, ati gbigba aaye igbaaya rẹ nibi fifi imọ mọ awọn ọmọde ati kikọ wọn ni ẹkọ.
Ninu awọn ẹkọ ounjẹ jíjẹ ni imaa jẹ ninu nkan ti o ba sunmọ eeyan, ayaafi ti o ba jẹ awọn iran orisirisi, nigba naa o le mu ninu rẹ.
Idunnimọ awọn saabe pẹlu nkan ti Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ba fi kọ wọn, wọn mu iyẹn jade lati ibi ọ̀rọ̀ Umar ti o sọ pe: Ìṣesí mi o wa yẹ lori ìyẹn lẹyin igba naa.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

