Ẹ paya abosi, nitori pe abosi jẹ awọn okunkun ni ọjọ igbedide, ẹ paya ahun, nitori pe ahun lo pa awọn ti wọn ṣáájú yin run,
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Jaabir ọmọ Abdullahi- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji- dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe: "Ẹ paya abosi, nitori pe abosi jẹ awọn okunkun ni ọjọ igbedide, ẹ paya ahun, nitori pe ahun lo pa awọn ti wọn ṣáájú yin run, o ti wọn lati maa ta awọn ẹjẹ wọn silẹ wọn si sọ awọn eewọ wọn di ẹtọ"
Explanation
Benefits
Ahun ati apọju ahun maa n ti ẹni lọ sibi ìyapa ati awọn ibajẹ ati ẹṣẹ.
Ìwòye si awọn isẹsi awọn ijọ ìṣáájú.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

