Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Mashood - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ".
Explanation
Benefits
Isọra nipa èṣù (Satani) eyi ti n ma joko sí gbogbo oju ona de ọmọniyan lati le dina laarin rẹ ati itẹle àṣẹ Ọlọhun Ọba to gbọngbọn ti O ga.
Ibn Hajar sọ pé: gbólóhùn rẹ tó sọ pé: (ko dide lọ kirun) ohun ti wọn gba lero ni iran, o sì lè túmọ sí ohun ti a ti bá sábà, irun òru tabi irun ọranyan ni wọn lè gbà lero.
At-Tiibiyy sọ pé: wọn da eti yan láti darukọ, bo tiẹ jẹ pe oju ni o ni ìbátan pẹlu orun, nitori ati tọkasi wíwọra orun naa, dájúdájú eti igbọrọ ni ààyè itaji, wọn si sa itọ yan; nitoripe ohun ni o rọrùn ju láti ko wọnu awọn iho, òhun sì ni ọ yara ju lati ta pọrọ wọnu isan ara, eyi ti yóò padà jogun oroju sí gbogbo orikerike ara.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

