wan tí fún mí ni nkán márùn tí wan kọ fún ẹni kánkan síwájú mí
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Láti ọdọ Jaabir ọmọ Abdullahi kí Ọlọhun yọnu sí awan méjèjì, dájú dájú anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá Rẹ má bà sọ pé: « wan tí fún mí ni nkán márùn tí wan kọ fún ẹni kánkan síwájú mí : wan fí ọwọ àti igbakẹ kankan mú aranse ba mí
Explanation
Alakọkọ: wan ràn mise pẹlu ìbẹrù tí wan nju sínú ọkan awàn ọtá mí , kò dá kí o já sipe kí Jinan mí sí ìbi tí wan wa le gbani ni irinajo osù kàn gbáko.
Ẹlẹẹkeji: wan se ilẹlẹ ni ààyè ifori kanlẹ fún wa tí a o máa kirun níbi kí bí tí a ba wa, wan tún se ni nkán imọra pẹlu lílo iyẹpẹ nígbàtí a bà kagara láti lọ omi.
Ẹlẹkẹta: wan se ọrọ ogún lẹtọ fún wa , òun ni nkan tí awàn musulumi nri gbà ní ojú ogún pẹlu awan alaigbagbọ.
Ẹlẹkẹrin: wan fun mí ni isipẹ tí o to bi jùlọ níbi ìfun awan ènìyàn ni ìsimi níbi ìbẹrù bojo ibuduro ọjọ igbende.
Ẹlẹkaarun: wan ràn mí sí gbogbo ẹda lapapọ àti eniyan àti alujannu wan yatọ sí ti awan anọbi tí wan síwájú rẹ, wan ran wan sí awan ìjọ wan nìkan ní .
Benefits
Ọlá Ọlọhun tí o gbangban tí o sí tóbi lórí ìjọ yí àti èyí to ṣe fún anọbi wa pẹlu awan nkán tí o da se fún wanyi.
Ṣíṣe kikun ni àsìko rẹ ní ọranyan pẹlu èyí k'eyi isesi tí kìí baa jẹ , àti ṣíṣe awàn nkán tí ipa ba ka nínú awani monjẹmu rẹ ati awon origun pẹlu ọranyan rẹ.
Orisirisi mí Isipẹ tí wan dá fun anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá Rẹ má bà láàrin awan anọbi : Alakọkọ ni : ṣíṣe ipẹ rẹ fún gbogbo ẹda láti ṣe ìdájọ láàrin won lasiko. Nínú rẹ ní isipẹ rẹ fún awán ọmọ alujanna láti wíwọ ọgbà idẹra , nínú rẹ tún ni : isipẹ rẹ fún ẹgban bàbá rẹ tii se Bàbá Tolib pé kí wan se ìyá rẹ ní fufu yẹ, , tí kí se isipẹ fún kí o jáde kúrò ninú inan, nítorípé o ku ni a lai gbagbọ .
Awan ìròyìn ẹsa anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba pọ tí wan ko darukọ nínú hadith ( ọrọ anọbi ) yí , nínú rẹ ní ; wan fún ní ìgbé ọrọ kalẹ tí yóò kò ọpọ nkán sínú, òun sí ni wan parí awan anọbi, wan si tún se tito ila wa lori Irun gẹgẹ bí tito ila awan iransẹ Ọlọhun (Malaikah ) àti awan ìròyìn ẹsa bẹbẹ lọ
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

