Ewo ninu iṣẹ ni Ọlọhun nifẹẹ si julọ? O sọ pe: "Irun kiki ni asiko rẹ", o sọ pe: Lẹyin naa èwo? O sọ pe: "Lẹyin naa ṣíṣe daadaa si awọn obi mejeeji" o sọ pe: Lẹyin naa èwo? O sọ pe: "Jija ogun si oju ọna Ọlọhun
Choose an available translation of this Hadeeth
Hadeeth text
Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Mas'ud- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Mo bi Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- leere pé: Ewo ninu iṣẹ ni Ọlọhun nifẹẹ si julọ? O sọ pe: "Irun kiki ni asiko rẹ", o sọ pe: Lẹyin naa èwo? O sọ pe: "Lẹyin naa ṣíṣe daadaa si awọn obi mejeeji" o sọ pe: Lẹyin naa èwo? O sọ pe: "Jija ogun si oju ọna Ọlọhun" o sọ pe: O sọ wọn fun mi, ti mo ba wa alekun rẹ dajudaju o maa ṣe alekun rẹ fun mi.
Explanation
Ọmọ Mas'ud- ki Ọlọhun yọnu si i- sọ pe: O sọ awọn iṣẹ yii fun mi; ti mo ba sọ fun un pe: Lẹyin naa èwo? Dajudaju o maa ṣe alekun rẹ fun mi.
Benefits
Ìṣe Musulumi lojukokoro lori iko akolekan lori awọn iṣẹ ti wọn dara julọ ati eyi ti o dara tẹle e.
Iyatọ awọn ìdáhùn Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nipa eyi ti o dara julọ ninu awọn iṣẹ wà ni ibamu si yiyatọ awọn eniyan ati awọn isẹsi wọn, ati eyi ti o pọ julọ ni anfaani fun gbogbo ẹni kọọkan ninu wọn.
Attribution
Categories
Share hadeeth
Sharing options · 0 Total shares

