Bi aṣen ṣe Aluwala olomi, ati Aluwala oni yẹpẹ, ati iwẹ

Apejuwe aluwala olomi ati oniyẹpẹ ati iwẹwẹ ghusl: Aworan rẹ ni ede Yoruba, Sheikh Dr. Haitham Sarhan lo pese rẹ, On bẹ ninu ẹ, ọrọ ṣoki nipa apejuwe aluwala olomi ati oniyẹpẹ ati iwẹwẹ ghusl ti Anabi, Ikẹ Olọhun ati ọla rẹ ko maa baa, pẹlu awọn aworan alapejuwe.

صفة الوضوء والتيمم والغسل:لوحة مصورة باللغة اليوربا ، من إعداد فضيلة الشيخ الدكتور هيثم سرحان، فيها ملخص صفة وضوء وتيمم وغسل النبي صلى الله عليه وسلم مع الصور التوضيحية.